352 Yoruba Proverbs, Sayings And Translations - Yoruba Project - 20 - 29 -#ireo #Irekabiti #edeYoruba #oweYoruba #AdebanjiOsanyingbemi

 20. Ṣé kí nfìdí hẹ?” làfòmọ́ fi ńdi onílé.


Yoruba Project


Purchase 352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project - https://amzn.to/3AFiMrz


“May I perch here awhile?” is the ruse by which the climber-parasite becomes a permanent resident.


Give people an inch, and they are liable to take several miles.


Complete Yoruba Course For Beginners - https://amzn.to/4dUeGKg



21. Àgbàlagbà tó bá fẹ́ fọ inú akèrègbè mọ́ gbọ́dò ṣ'ọ̀rẹ́ ọmọdé, bẹ́ẹ̀ náà ni ọmọdé tó bá fẹ́ mú nǹkan lórí pẹpẹ gbọdọ̀ sún mọ́ àgbàlagbà nítorí ọwọ́ ọmọdé ò tó pẹpẹ t'àgbàlagbà ò wọ akèrègbè.


An elderly person who wants to wash the inside of a gourd, clean, must befriend a child; so also a child who wants to retrieve something on a high shelf must be close to an elder, because a child's hand cannot reach a shelf; and that of an elder won't enter a gourd.


Yoruba Project - Videos 11 - 20


No one can do it all; we do need one another; cooperate and collaborate more.


Buy - Yoruba For Kids - https://amzn.to/3TtETIa


22. Olówe laláṣẹ̀ ọ̀rọ̀.


A person who knows proverbs has the last word in a dispute.


Buy - Speak Yoruba In A Day - https://amzn.to/3XvNQ5Z


There is no authority like proverbial authority.



23. Ìjàpá ńlọ sájò, wọ́n ní ìgbà wo ni yó dèé, ó ní ó dìgbàtí òún bá tẹ́.


Tortoise set out on a journey and it was asked when it would return; it replied that it would be after it had earned disgrace.


Yoruba Project Videos - 21 - 30


Certain people will not change course until they are disgraced.


Great Online International Money Transfer


24. Nǹkan mẹ́ta la kì í pè ní kékeré: a kì í pe iná ní kékeré; a kì í pe ìjà ní kékeré; a kì í pe àìsàn ní kékeré.


Three things one must never treat as of little consequence: one must never treat fire as of little consequence; one must never treat a quarrel as of little consequence; and one must never treat an illness as of little consequence.


One must attend to every potential problem early before it gets out of hand.


Help rebuild Old Kent Road Mosque 


25. Ẹ gún ẹṣin ní kẹ́ṣẹ́, ẹ ló ńtà'pá, baba ta ni wọ́n máa ki irin bọ̀ ní'kùn tí kò ní ju apá? 


You spurred a horse and wondered why it kicked; who would be struck with steel in the belly and not react?


Be fair; be considerate; treat others as you would want to be treated!



26. Ẹni tí a ò lè mú, Ọlọ́run là ńfi lé lọ́wọ́.


An adversary over whom one cannot prevail, one leaves to God's judgement.


If an adversary is too much for one, one sets God at him or her.



27. A kì í fi ohun-olóhun tọrẹ bí kò ṣe tẹni.


One does not make a gift of someone else's property when it is not one's own.


Never be too free with other people's property.



28. Kí ni ìyá aláṣọ ńtà tó yọ ẹgba lọ́wọ́? Ewúrẹ́ ńjẹ wúlìnì?


What is the cloth-selling woman have to sell that she carries a whip in her hand?

Do goats eat woolen fabrics?


One should not engage in meaningless or unnecessary activities.



29. Wọ́n ní kárúgbó gba ọmọ pọ̀n, ó ní ṣe bí wọ́n mọ̀ pé òun ò léhín; wọ́n ní kó pa ọmọ jẹ ni?


The old woman is asked to carry a child on her back, and she says but they know she has no teeth; was she asked to eat the child.


Said of people whose comment on a proposition is wildly irrelevant.


Purchase the book?


Watch the videos?


Buy similar books - https://amzn.to/3UDAhP6


https://amzn.to/3WGy8oE


We do Affiliate Marketing, and earn commissions for each sale, at no additional cost to you.


Comments

Popular posts from this blog

352 Yoruba Proverbs, Sayings And Translations - Yoruba Project - 1-9 - #oweYoruba #edeYoruba #ireo #Irekabiti #AdebanjiOsanyingbemi

352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project - 290 - 299 - Adebanji Osanyingbemi - Olayinka Carew - Jack Lookman #ede Yoruba

352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project 340 - 352 Adebanji Osanyingbemi - Olayinka Carew - Jack Lookman - ede Yoruba