352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project 340 - 352 Adebanji Osanyingbemi - Olayinka Carew - Jack Lookman - ede Yoruba
340. Ẹni tò ṣu ló gbá gbé, ẹnì tó fi ọ̀wọ́ koo o lé gbágbé Buy - 352 Yoruba Proverbs Sayings And Translations - Yoruba Project - https://amzn.to/4cTuyMl The one who defecated might forget but he who packed it with his hands will not He who starts a trouble might not feel the impact like the one who bears the brunt of such trouble Complete Yoruba Course For Beginners - https://amzn.to/4dUeGKg 341. Ọbá mẹ̀wá, igbá mẹ̀wà ẹ́nikán ki'lé ló ilé àyé gboo Ten kings, ten seasons, will not see the end of the world No condition is permanent 342. Rírò ni ti ẹ̀nìyàn ṣíṣe ni ti Olúwa Man can only think but the doing/actualization is of God Man proposes God disposes 343. Ọgbọ́n kìí tán ,ki á wa lọ́ si ọ́run The world cannot be bereft of wisdom that we have to go to heaven There are solutions to every situation 344. Aà rin nilẹ́ inu bi ẹlẹ́ṣin,a n wọ́ akiṣá inu bi àláṣọ, a n jẹ́ ẹ́fọ̀ sun inu bi ẹ́lẹ̀ran We walk on ground and the horseman gets angry, we put on rag